Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn Profile Banner
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn Profile
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn

@YusuffOpeere

Followers
498
Following
377
Media
173
Statuses
2,264

yusuffopeere @gmail .com, or call +2347052932707

Nigeria
Joined January 2022
Don't wanna be here? Send us removal request.
Explore trending content on Musk Viewer
Pinned Tweet
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
3 months
If you don't understand, read the captions.
8
29
110
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
Mo wá láti ìlú Ìṣẹ́yìn, ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.
Tweet media one
@eludayo_1
𝓔𝓵𝓾𝓭𝓪𝔂𝓸 𝓑𝓲𝓫𝓲𝓽𝓪𝔂𝓸 ♥︎
1 year
I am from Ile-Ife 💯❤️ and U?
Tweet media one
469
84
764
140
251
3K
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
3 months
Happy birthday to me. May I live longer in bliss.
Tweet media one
36
31
420
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
Èmi lọmọ tí wọn ń ṣọ.
Tweet media one
@instablog9ja
Instablog9ja
1 year
Fine Yoruba men, let's have that hot picture
1K
112
2K
0
10
81
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
Ìṣẹ́yìn, Ọmọ Ẹbẹdí mọkọ, Ìlú ẹ̀yẹ́ kìkì àpọ́nlé.
Tweet media one
@FotoNugget
SarkinFOTO
1 year
If you’re from Oyo State—Drop your photo & exactly where you’re from—I go first; I’m from Ibadan, Oyo State! 💎😊
Tweet media one
2K
283
2K
2
0
26
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
@CyntroG It's blurry. I will reply your message when my visitor leave.
Tweet media one
0
0
26
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
3 months
It's my thirtieth birthday today. So I really need help. I want to begin a new life.
3
8
23
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
@wuraindabewrinn We are holding such a program.
Tweet media one
3
6
21
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
I'm 29 today. Happy birthday to me. May I till death live longer in pure bliss.
Tweet media one
Tweet media two
10
1
22
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
2 years
0
0
18
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
23 days
Last Sunday, I in person connected with one of Ibadan-based content creators @visitmas at #Yorubaparty organized by @egbeatelewo and @theayoadams . The guy really has steeze and rizz, and a lot of pizzazz one needs to be eminent in one's career. 1/2
Tweet media one
1
5
18
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
5 months
0
0
15
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
5 months
Tweet media one
Tweet media two
0
3
16
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
5 months
Àkókò tí mò ń béèrè ìbéèrè lọ́wọ́ @animolenikun níbi àyájọ́ ọjọ́ èdè abínibí lágbayé àti fífi àmì ẹ̀yẹ dá àwọn òǹkọ̀wé mẹ́rin tó peregedé jùlọ lọ́lá, èyí tí @egbeatelewo ṣe àgbékalẹ̀ rẹ̀ ní ọjọ́ kẹsàn-án, oṣù Èrenà nínú ọgbà fáṣítì ti Ìbàdàn.
Tweet media one
1
4
17
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
2 years
0
0
14
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
You can only understand why I have 'yellow teeth' if you were raised by any of your grandparents. In the village, there's no toothpaste and toothbrush, it is either you cut the stems or roots of 'prescribed' trees and use it to clean your teeth. Or foam and ashes, and/or salt.
Tweet media one
4
1
15
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
These days, my attention has been drawn to culture and language, Yorùbá to be precise. I have started losing interest in what does not belong to my origin. And I implore you all to start doing so regardless of your religion. I am Oòduà. I cannot in anyway deny that. 1/3
3
2
14
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
Gẹ́gẹ́ bí ọmọ Oòduà, èdè, àṣà àti ìṣe wa yẹ kí ó j'ọba loókan àyà wa. Kìí ṣe orí àtẹ ayélujára nìkan ni a ó ti máa ṣe èyí bí kò ṣe pé yóò máa hàn nínú ìwọsọ wa, ìkọ̀wé wa, ìbánisọ̀rọ̀, ìṣòwò, ìkíni; eléyìí wulẹ̀ ti tàbùkù wa púpọ̀. Ẹ káààrọ̀, ẹ káàsán, abbl
Tweet media one
0
5
14
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
Akínkanjú ẹ̀dá ló ń ní owó Akin ọmọ ní ń ya akin Ẹ̀dá tí àforítì ò sí lẹ́rù rẹ̀ Irú wọn kìí yàn're lókè èèpẹ̀ Bí a bá ti nísẹ́ tó dára lọ́wọ́ Ẹ jẹ́ a múra kí ó f'ẹsẹ̀ múlẹ̀ K'Ólúwa ó wà jọ́rẹ̀ẹ́ kòríkòsùn wa Èmi ò ní kò s'áyé, ibi a bá gun'gi làá bá sọ̀.
Tweet media one
1
3
14
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 month
If you're planning to venture into agribusiness (cassava and maize), stay tuned
2
10
14
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
Eid mubarak: We are friends this year. Wish we are a couple next year.
Tweet media one
2
0
13
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
5 months
Mò ń lọ sí ibi àjọ̀dún @egbeatelewo nínú gbọ̀ngàn Youth Center, UI Ibadan.
Tweet media one
1
4
13
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
@wolfintinct It's been long you have chopped hot slaps sir?
1
0
12
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
3 months
@tyewoolove Ti n bá sọ pé A Agbára káká kọ́ la fí ń kọrin tia, A Àgbàrá nlá kọjá níta bàbá ọ̀bà Ó pa àdàbà falágbára Agbada ni ìyá fi ń dín'kàrà Ẹ sọ fún bàbá alágbádá Kó rọra létí agbada Àlàájà tó ń ta shawa Shawa gbangba Àgbàlagbà l'Abíọ́lá Abíọ́lá alárà gbàyídá...
1
0
13
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
3 months
Ẹni máa rí ire á ṣe ìbà òwúrọ̀.
Tweet media one
Tweet media two
1
2
12
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
@SPIIRIT_MAN You never chop slaps before?
1
1
11
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
If the British people who colonized us are not tribalistic, I would not have written this in language that is not mine. Yorùbá dùn! Trust me, you and I have powerful and beautiful names that the white people would so love and envy of christening their kids if they hear it. 3/3
Tweet media one
1
1
12
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
2 years
1
0
11
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
Òyìnbó kò kàn án 'nípá'fún ìran rẹ̀ láti máa sọ èdè àjòjì, wọ aṣọ ilẹ̀ òkèèrè tàbí jẹ oúnjẹ míràn yàtọ̀ sí ti ìran baba wọn. Kìí ṣe àìmọ̀ọ́kọ tàbí àìmọ̀ọ́kà, ṣùgbọ́n èmi ò kú lórí bíi púpọ̀ àwa ọ̀dọ́ ìwòyí ṣe rí. Èdè Yorùbá dùn. Àṣà Yorùbá ṣe é mú yangàn.
Tweet media one
1
2
11
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
2 years
Èmi pẹ̀lú Ọ̀gbẹ́ni @theayoadams rè é lọ́jọ́ náà lọ́hùn ún.
Tweet media one
1
1
10
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
I'm coming back to teach you more about it.
Tweet media one
0
3
10
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
2 months
Let's return to village to practice farming, if you don't have time for it I can help you.
0
4
10
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
@191Introvert Anything wrong with it?
1
0
10
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
2 months
First of all,... Eid Mubarak to you all.
Tweet media one
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
Eid mubarak: We are friends this year. Wish we are a couple next year.
Tweet media one
2
0
13
0
1
9
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
5 months
0
0
7
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
2 years
Maybe it would have been better than this if people could stop predicting the content of me by my appearance. 📷: @theayoadams
Tweet media one
1
1
9
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
5 months
0
0
6
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
If you like you can laugh. I don't mind. I'm a producer of all what you consume. I am a farmer. I do this to survive. Ó sàn ju olè lọ.
1
0
8
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
3 months
Ti n bá sọ pé A Agbára káká kọ́ la fí ń kọrin tia, A Àgbàrá nlá kọjá níta bàbá ọ̀bà Ó pa àdàbà falágbára Agbada ni ìyá fi ń dín'kàrà Ẹ sọ fún bàbá alágbádá Kó rọra létí agbada Àlàájà tó ń ta shawa Shawa gbangba Àgbàlagbà l'Abíọ́lá Abíọ́lá alárà gbàyídá...
@tyewoolove
Bọ́láńlé oní story 🖋️
3 months
Alhaji Pasuma once said…….
Tweet media one
267
57
507
0
4
8
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
@bossladyofLagos You don't at all resemble Yorùbá daughter if you are, where is the culture? Fashion, for instance.
23
0
6
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
@Walmart1805 Sáà send my share when you're done with it
0
0
6
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
0
1
7
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
2 years
Mo pe gbogbo yín o. Ẹ wá síbi àpérò yìí lọ́jọ́ kàrún ún Oṣù Kejì ọdún Ẹgbàá ó lé mẹ́talélógún (5/02/2023) ní ìlú Ìṣẹ́yìn.
Tweet media one
2
1
6
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
I have seen the only reason I have to take a loan from PalmPay. 🤳 @Akinosun615 @Omo_Makinde àti @_adenikehammed ni oníìdúro mi.
Tweet media one
2
0
7
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
🤣🤣🤦🤦🤦
Tweet media one
0
0
7
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
2 months
@AramideOyekunle Oyo State; I will pick Iseyin town. I'm sure by God's grace before the end of the year I will be a landlord. A room-and-parlor self-contained costs a hundred thousand naira or and a half in Iseyin.
2
1
7
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
@HPotables Ó sún mọ́ ara wọn. Ṣé Òkè'hò ni ẹ wà báyìí?
2
0
7
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
2 months
I don't think you can survive without farmers, if can, I will wait for you in the comment section. Let's drag it.😋😋😛
0
0
7
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
Àgbẹ̀ - Farmer.
1
1
6
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
@Dharmmie001 Ẹ ṣeun
0
0
7
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
8 months
Owó tó ń wọlé kò tó mi ní níná fún jíjẹ àti mímu, kí á tó sọ pé n ó r'aṣọ sára, gbọ́ ti ẹbí, bun àwọn ènìyàn. Háà, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà yìí le koko bi ojú ẹja. Bẹ́ẹ̀ àmù tó ti kún ni àwọn ọlọ́lá wa gbogbo tún ń pọn omi sí. Olódùmarè má jẹ́ kí ó nira fún mi o!
Tweet media one
0
1
7
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
3 months
In my next video, I want to advice the newbies who are coming into Agri business. Anticipate!!! Don't forget to retweet this.
0
3
6
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
2 years
Àwọn ènìyàn iyì. @ShugabanR and @rasaq_malik
Tweet media one
Tweet media two
0
0
6
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
2 years
I, Yusuff Ọ̀pẹẹrẹ is a crop Farmer. I help people in managing their farm. I help them in planting, weeding and harvesting.
Tweet media one
Tweet media two
Tweet media three
Tweet media four
@UnclebeeOla
Abd Basit The Big Asset♥️
2 years
Oya, let's do a vendor and what you sell thread. Quote this with a picture of you and what you sell with a short intro too.
79
36
101
0
3
6
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
2 months
2
0
6
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
4 months
Anticipate!!!
0
0
6
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
2 months
Where I've Been, Isn't Where I'm Going.
Tweet media one
0
0
6
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
Of what use is the stone on the lid of pot when we are boiling yams? @AdejokeEwaede @arabinrinrahmah @AzeezElugoke @DunLenu @FIjinle @ewagoyin_tide
2
1
6
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
Good morning, and happy father's day.
Tweet media one
0
1
6
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
5 months
I wish I own one.
Tweet media one
@quinndiamond1_
Diamond Hamdalah💎🤎❤️🌹
5 months
If you're still awake, Quote or reply with anything in your gallery!!!
6
3
23
1
1
6
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
5 months
Mo l'áyọ̀ láti sọ fún un yín pé èmi pẹ̀lú ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ ọmọ káàárọ̀-o-jíire bí tó ní ìfẹ́ púpọ̀ sí èdè abínibí wa, Yorùbá yẹ́ ìpè @egbeatelewo sí nípa wíwà ní ìkàlẹ̀ lónìí nínú gbọ̀ngàn Youth Center, UI Ìbàdàn níbi tí ẹgbẹ́ náà ti fi àmì ẹ̀yẹ olówó iyebíye dá 1/2
Tweet media one
1
3
5
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
8 months
Ẹ̀mí mi á gùn pẹ̀lú Olódùmarè. Ìwọ ńkọ́?
Tweet media one
2
0
6
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
I was a little bit pleased with Nigerian government the last time I was at the station. Many thingies were there abandoned. 😭😭💔💔
@theayoadams
Ayo of Ibadan
1 year
Ibadan.
Tweet media one
Tweet media two
9
34
86
2
2
5
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
The tribal marks on my cheeks are sure-enough depiction of where I come from anywhere I find myself. The accent. The color. Everything that differentiate us from others. And I have never been ashamed of myself amidst other tribes. I always feel proud of these tribal marks. 2/3
1
1
6
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
You're my crush. But I know you will be chasing either political bigwig or Cleric or Yahoo guy. @arabinrinrahmah
Tweet media one
@arabinrinrahmah
Iyalode Awon Boiz
1 year
Ladies and gentlemen, who's your crush for today? Here's mine Woman Crush Wednesday 😍 Quote retweet with yours.
Tweet media one
Tweet media two
Tweet media three
Tweet media four
10
6
98
9
0
6
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
2 months
@MyHeartcode No waste time with the woman who doesn't understand me.
2
1
5
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
4 months
0
0
5
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
@arabinrinrahmah In-between the two. Olúwa ló ni ẹ̀mí àwa àgbẹ̀.
Tweet media one
1
0
5
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
2 months
Ẹkùn ọkọ 'mọlará.
Tweet media one
@dotboyswag10
DotBoy😈🔥
2 months
Can we see your outfit to Eid??
21
30
73
0
0
5
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
6 months
2014 🧑‍💻
Tweet media one
@IamTommivill
Mr Tom
6 months
2004 🌚
Tweet media one
42
24
174
0
0
5
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
The Photographer vs The photography
Tweet media one
Tweet media two
@diddi_uk
Diddi📸💖
1 year
The photographer vs the photo.
Tweet media one
Tweet media two
37
154
2K
0
2
5
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
@jahsaint1 I don't think so. Iseyin is large fah.
1
0
4
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
11 months
Inú a dùn láti pẹ̀lú yín nínú ìrìn-àjò àfẹ́ lọ sí ìlú Àwáyè lẹ́bàá ìlú mi, Ìṣẹ́yìn. Olódùmarè yóò dá ẹ̀mí wa sí ju ìgbà náà lọ. @sam_aderoju @Iseyin_Connect @badruafees34
@emmylyskilzpro1
Emmyly 02
11 months
2 in 1. A road trip to Ado Awaye and you also get a free ticket to see my next play Ẹbọra Òru. Send a DM to @FunMongers_ng to get your tickets. #ẸbọraÒruInIbadan
Tweet media one
0
20
15
0
2
5
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
2 years
Àkókò rè é láti ṣe ìpolówó ara mi fún ìgbà àkọ́kọ́ ní orí ìkànnì abẹ́yẹfò. Ẹ̀yin ènìyàn mi, orúkọ mi ni Yusuff Ọ̀pẹẹrẹ, mo jẹ́ òǹkọ̀wé ní èdè Yorùbá àti èdè Gẹ̀ẹ́sì, mo ti kọ ìwé tó bíi orísìí mẹ́ta sí mẹ́rin ṣùgbọ́n mi ò tíì ní ànfààní láti gbé ọ̀kankan jáde
Tweet media one
1
2
4
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
When you have PHD in photoshop. 🤣🤣🤣🤣🤣
Tweet media one
0
0
5
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
"Kò ni mí lára láti fún gbogbo yín ní ohun tí ẹ̀ ń béèrè fún. Bí ó bá ṣe pé owó ni ẹ bìkítà fún, mo le yá owó láti fún un yín. Ṣùgbọ́n ẹ rántí pé bí a bá dìbò tí a wọlé, kò ní le è sí ọ̀nà tó já gaara, omi ẹ̀rọ, iná mọ̀nàmọ́ná, ètò ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́,
1
2
5
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
5 months
Olódùmarè gba ọkàn ẹnìkan ṣe mí lóore láìpẹ́ ọjọ́. Fi owó wá mi rí.
3
2
5
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
3 months
Lọpẹ́lọpẹ́ camera, àbámámọ̀ pé èmi náà wá. Èmi nùu ní ẹ̀gbẹ́ ẹ̀gbọ́n mi @theayoadams tí mò sí yẹ̀rì ètè bí àgbàdo inú ẹ̀ẹ̀rùn.
@visitmas
MAS
3 months
My Twitter Interaction Circle ➡️
Tweet media one
13
8
25
1
2
5
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
@AdejokeEwaede Ọ̀rọ̀ yìí gba omi lójú mi, bẹ́ẹ̀ ẹ̀wẹ̀ ó tún dá ẹ̀rín pa ẹ̀rẹ̀kẹ́ mi. Nítorí pé bí ìgbà tó ṣe pé èmi èmi ni ẹ dojú àṣamọ̀ yín kọ ni. Ọ̀rọ̀ náà ní iye lórí púpọ̀. Èdùmàrè á ya gbogbo wa ní ènìyàn.
1
0
5
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
Ọ̀kan lára àwọn ìdí pàtàkì tí èmi pẹ̀lú àwọn bíi mélòó kan ṣe gbé ètò GBÀGEDE ÀṢÀ ÀTI ÌṢE ỌMỌ OÒDUÀ kalẹ̀ nìyí.
Tweet media one
@YorubaDunLeti
Èdè Yorùbá Dùn Létí
1 year
Ẹ gbé èdèe Yorùbá láruge 👇
Tweet media one
2
6
16
0
3
5
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
2 years
Wow!
@Abiso_la
~Thonia🦋
2 years
Tried this football challenge in a school area😂🔥 Guys. Please Retweet🙏🏽
1K
8K
22K
0
1
5
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
10 months
@egbeatelewo À ní sẹ́, èdè Yorùbá dùn púpọ̀. Ẹ kú kí àṣà Yorùbá má parun.
0
0
5
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
5 months
To all the causes that make me address myself as a poet, Happy World Poetry Day. (This is my first work to be appeared in magazine.)
Tweet media one
0
1
5
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
@FIjinle Báwo ni mo ṣe le rí ìwé náà rà?
1
0
5
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
Yesterday, I was somewhat floored by my well-wishers — political bigwigs, educational kingpins and Media VIPs. The wishes I got from them reduced me to tears. I was not expecting that. 1/2
Tweet media one
1
0
5
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
Earlier today, I was at the 'marriage ceremony' of my leader, mentor, friend and more @sam_aderoju in Iseyin. I am thrilled to be inn attendance, and I pray for the couple, may Allah bless their union. And may they not be EX to each other in future.
1
1
5
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
2 years
If you're from Iseyin and you don't know Aunty Adijat, gbàgbé, you don't know person who is amiable. @mukailaaderoju5 @asookeiseyinent @IamJauntyman @badruafees34 @omoalhajaabiola
Tweet media one
1
0
4
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
I ain't a product. I am a producer. I have a good conduct. I am a farmer.
1
1
5
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
27 days
One gorgeous lady was ogling me at #Yorubaparty but I quickly told myself, "Ọmọlará is waiting for me at home." Mo ya look away. 😂😂😂 cc: @egbeatelewo
0
1
4
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
Ní nǹkan bíi agogo méjọ ìrọ̀lẹ́ àná, mo rí ìwé yìí gbà láti ọwọ́ bàbá mi n nì @FIjinle . Gẹ́gẹ́ bí àwọn tìka alára ti sọ nínú ọ̀rọ̀ ìfijúbà, "ìlànà ìkọ̀wé D. O. Fágúnwà àti Alàgbà Adébáyọ̀ Fálétí ni ìwé náà tẹ̀lé" pẹ̀lú ohun ti mo ka nínú "Abala tó di àfẹ́kùn."
0
0
5
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
4 months
Ibi a gbé ti bí ni kò ṣe é fi pamọ́. Inú agbo ọ̀gẹ̀dẹ̀ ni ilé ìyàgbẹ́ ti wa; ìdọ̀tí á kún gbogbo ẹ̀kùnlé bí òjò bá ṣẹ̀ṣẹ̀ dá. Kò sí ilé ìwẹ̀ ìgbàlódé, omi ẹ̀rọ kò wọ́pọ̀ ní àdúgbò wa.
Tweet media one
Tweet media two
0
0
4
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
@CLADBYNAHS I do not believe that.
2
0
3
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
2 months
1. Àìní àkíyèsí ló fa ìjàmbá alùpùpù mi. 2. Bí kìí bá ṣe pé mo ní àkíyèsí ni, igi náà kò bá gún mi lójú. 3. Àkíyèsí ni Àyìnkẹ́ kò ní ló ṣe pàdánù ẹ̀mí ọmọ rẹ̀ sọ́wọ́ àìsàn gìrì. 4. Mo ṣe àkíyèsí àìlọ déédé nǹkan fún ọ̀gá mi. 5. Adé pé àkíyèsí mi sí àwọn àṣìṣe mi.
@LekanFabilola
Ọlálékàn.
2 months
In this class, I taught about Àkíyèsí, meaning and how to use it in #Yoruba #language . Do the assignment, reward for the first three good answers.
30
200
527
0
2
4
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
5 months
@eludayo_1 10 years ago as a labourer.
Tweet media one
1
0
4
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
I want you to blow me away like wind, Or stream 'cause like rain, I fell for you
@Dr_zheen
Dr_zheen_shot
1 year
“Like rain, I fell for you” 💙🤍
Tweet media one
Tweet media two
Tweet media three
Tweet media four
36
65
608
0
0
3
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
11 months
I can do this. But who and where is the 'best fit' opposite?
@emmylyskilzpro1
Emmyly 02
11 months
I look forward to receiving your entry. 😁 See the script in the thread. #ẸbọraÒruInIbadan
14
47
87
0
2
4
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
1 year
@AishahAyilara Aisha, tell me more about this. I'm a crop farmer.
1
0
4
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
2 years
@tolul_ope In case you urgently need a 'qualified' graphic designer. 24/7 service nationwide.
Tweet media one
0
0
3
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
2 years
It's a great pleasure to meet you sir. Thanks for the visit
@theayoadams
Ayo of Ibadan
2 years
Tweet media one
0
1
8
1
1
4
@YusuffOpeere
Ọkùnrin àgbẹ̀ ìlú Ìsẹ́yìn
4 months
@YorubaDunLeti @yoruba_proverbs @Akinkunmialab10 @egbeatelewo @Dapsyroy @folakearemu5 @kzm9691 @ibadan_pikin Háà, kí ẹ sì máa wò ó, mo mọ òwe náà ṣùgbọ́n n ò rántí ní àkókò n nì.
2
2
4